Listen to this chapter • 1:03
[1] Ẹ pàtẹ́wọ́, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn ẹ hó sí Ọlọ́run pẹ̀lú orin ayọ̀ tó rinlẹ̀.
[2] Báwo ni Olúwa Ọ̀gá-ògo ti ní ẹ̀rù tó ọba ńlá lórí gbogbo ayé.
[3] Ṣe ìkápá àwọn orílẹ̀-èdè lábẹ́ wa àwọn ènìyàn lábẹ́ ẹsẹ̀ wa
[4] Ó mú ilẹ̀ ìní wa fún wa, ọlá Jakọbu, ẹni tí ó fẹ́ wa.
[5] Ọlọ́run tó gòkè lọ tí òun tayọ̀, Olúwa ti òun ti ariwo ìpè.
[6] Ẹ kọrin ìyìn sí Ọlọ́run, ẹ kọrin ìyìn. Ẹ kọrin ìyìn sí ọba wa, ẹ kọrin ìyìn!
[7] Nítorí Ọlọ́run ni ọba gbogbo ayé, ẹ kọrin ìyìn pẹ̀lú Saamu!
[8] Ọlọ́run jẹ ọba lórí gbogbo kèfèrí; Ọlọ́run jókòó lórí ìtẹ́ ìwà mímọ́ rẹ̀.
[9] Àwọn aládé ayé kó ara wọn jọ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn Ọlọ́run Abrahamu nítorí asà ayé ti Ọlọ́run ni, òun ni ó ga jùlọ.
Ìwé Saamu — Chapters
10:5621:2230:5841:1951:4961:2072:0481:0792:25102:34111:04121:09130:54141:05150:51161:29172:05185:58191:59201:12211:43224:09230:53241:16252:27261:25272:13281:23291:10301:38313:22321:41332:15342:26353:48361:38374:42382:24392:05402:57411:39422:01431:00443:10452:27461:24471:03481:40492:29502:49512:28521:31531:10541:05553:08561:46571:48581:35592:36601:46611:02621:42631:23641:27651:54662:09670:52684:40694:17700:51712:59722:36732:54742:48751:24761:32772:22787:13791:45802:10811:52820:57831:54841:35851:23861:54870:52882:05895:09902:01911:45921:37930:42942:16951:18961:29971:15981:01991:071000:361011:111022:481032:071044:041054:131065:081074:211081:371093:331101:011111:101121:221130:591140:511151:531161:551170:181182:4311916:011200:421210:481220:571230:381240:491250:491260:431270:481280:471290:561300:501310:371321:551330:341340:261352:041362:151371:061381:061392:461401:391411:251421:071431:381442:041452:021461:101471:591481:361491:021500:41