Listen to this chapter • 0:57
[1] Inú mi dùn nígbà tí wọ́n wí fún mi pé, “Ẹ jẹ́ kí á lọ sílé Olúwa.”
[2] Ẹsẹ̀ wa yóò dúró ní ẹnu ibodè rẹ, ìwọ Jerusalẹmu.
[3] Jerusalẹmu, ìwọ tí a kọ́ bí ìlú tí o fi ara mọ́ra pọ̀ ṣọ̀kan.
[4] Níbi tí àwọn ẹ̀yà máa ń gòkè lọ, àwọn ẹ̀yà Olúwa, ẹ̀rí fún Israẹli, láti máa dúpẹ́ fún orúkọ Olúwa.
[5] Nítorí ibẹ̀ ni a gbé ìtẹ́ ìdájọ́ kalẹ̀, àwọn ìtẹ́ ilé Dafidi.
[6] Gbàdúrà fún àlàáfíà Jerusalẹmu; àwọn tí ó fẹ́ ọ yóò ṣe rere.
[7] Kí àlàáfíà kí ó wà nínú odi rẹ̀, àti ìre nínú ààfin rẹ̀.
[8] Nítorí àwọn ọkùnrin àti àwọn ẹgbẹ́ mi èmi yóò wí nísinsin yìí pé, kí àlàáfíà kí ó wà nínú rẹ̀.
[9] Nítorí ilé Olúwa Ọlọ́run wa, èmi yóò máa wá ìre rẹ̀.
Ìwé Saamu — Chapters
10:5621:2230:5841:1951:4961:2072:0481:0792:25102:34111:04121:09130:54141:05150:51161:29172:05185:58191:59201:12211:43224:09230:53241:16252:27261:25272:13281:23291:10301:38313:22321:41332:15342:26353:48361:38374:42382:24392:05402:57411:39422:01431:00443:10452:27461:24471:03481:40492:29502:49512:28521:31531:10541:05553:08561:46571:48581:35592:36601:46611:02621:42631:23641:27651:54662:09670:52684:40694:17700:51712:59722:36732:54742:48751:24761:32772:22787:13791:45802:10811:52820:57831:54841:35851:23861:54870:52882:05895:09902:01911:45921:37930:42942:16951:18961:29971:15981:01991:071000:361011:111022:481032:071044:041054:131065:081074:211081:371093:331101:011111:101121:221130:591140:511151:531161:551170:181182:4311916:011200:421210:481220:571230:381240:491250:491260:431270:481280:471290:561300:501310:371321:551330:341340:261352:041362:151371:061381:061392:461401:391411:251421:071431:381442:041452:021461:101471:591481:361491:021500:41