Listen to this chapter • 0:47
[1] Ìbùkún ni fún gbogbo ẹni tí ó bẹ̀rù Olúwa: tí ó sì ń rìn ní ọ̀nà rẹ̀.
[2] Nítorí tí ìwọ yóò jẹ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ ìbùkún ni fún ọ; yóò sì dára fún ọ.
[3] Obìnrin rẹ yóò dàbí àjàrà rere eléso púpọ̀ ní àárín ilé rẹ; àwọn ọmọ rẹ yóò dàbí igi olifi tí ó yí tábìlì rẹ ká.
[4] Kíyèsi i pé, bẹ́ẹ̀ ni a ó bùsi i fún ọkùnrin náà, tí ó bẹ̀rù Olúwa.
[5] Kí Olúwa kí ó bùsi i fún ọ láti Sioni wá, kí ìwọ kí ó sì máa rí ìre Jerusalẹmu ní ọjọ́ ayé rẹ gbogbo.
[6] Bẹ́ẹ̀ ni kí ìwọ kí ó sì máa rí àti ọmọdọ́mọ rẹ. Láti àlàáfíà lára Israẹli.
Ìwé Saamu — Chapters
10:5621:2230:5841:1951:4961:2072:0481:0792:25102:34111:04121:09130:54141:05150:51161:29172:05185:58191:59201:12211:43224:09230:53241:16252:27261:25272:13281:23291:10301:38313:22321:41332:15342:26353:48361:38374:42382:24392:05402:57411:39422:01431:00443:10452:27461:24471:03481:40492:29502:49512:28521:31531:10541:05553:08561:46571:48581:35592:36601:46611:02621:42631:23641:27651:54662:09670:52684:40694:17700:51712:59722:36732:54742:48751:24761:32772:22787:13791:45802:10811:52820:57831:54841:35851:23861:54870:52882:05895:09902:01911:45921:37930:42942:16951:18961:29971:15981:01991:071000:361011:111022:481032:071044:041054:131065:081074:211081:371093:331101:011111:101121:221130:591140:511151:531161:551170:181182:4311916:011200:421210:481220:571230:381240:491250:491260:431270:481280:471290:561300:501310:371321:551330:341340:261352:041362:151371:061381:061392:461401:391411:251421:071431:381442:041452:021461:101471:591481:361491:021500:41