Listen to this chapter • 1:00
[1] Dá mi láre, Ọlọ́run mi, kí o sì gba ọ̀rọ̀ mi rò lọ́dọ̀ àwọn aláìláàánú orílẹ̀-èdè: yọ mí kúrò lọ́wọ́ ẹlẹ́tàn àti àwọn ènìyàn búburú.
[2] Ìwọ ni Ọlọ́run ibi agbára mi. Èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ mi sílẹ̀? Èéṣe tí èmi yóò máa rìn nínú ìbìnújẹ́, nítorí ìnilára lọ́dọ̀ àwọn ọ̀tá?
[3] Rán ìmọ́lẹ̀ àti òtítọ́ rẹ jáde, jẹ́ kí wọn ó máa dáàbò bò mí; jẹ́ kí wọn mú mi wá sí òkè mímọ́ rẹ, sí ibi tí ìwọ ń gbé.
[4] Nígbà náà ni èmi ó lọ sí ibi pẹpẹ Ọlọ́run, sí Ọlọ́run ayọ̀ mi àti ìdùnnú mi, èmi yóò yìn ọ́ pẹ̀lú dùùrù, ìwọ Ọlọ́run, Ọlọ́run mi.
[5] Èéṣe tí o fi ń rẹ̀wẹ̀sì, ìwọ ọkàn mí? Èéṣe tí ó fi ń ru sókè nínú mi? Fi ìrètí rẹ sínú Ọlọ́run, nítorí èmi yóò máa yìn ín, Òun ni Olùgbàlà mi àti Ọlọ́run mi.
Ìwé Saamu — Chapters
10:5621:2230:5841:1951:4961:2072:0481:0792:25102:34111:04121:09130:54141:05150:51161:29172:05185:58191:59201:12211:43224:09230:53241:16252:27261:25272:13281:23291:10301:38313:22321:41332:15342:26353:48361:38374:42382:24392:05402:57411:39422:01431:00443:10452:27461:24471:03481:40492:29502:49512:28521:31531:10541:05553:08561:46571:48581:35592:36601:46611:02621:42631:23641:27651:54662:09670:52684:40694:17700:51712:59722:36732:54742:48751:24761:32772:22787:13791:45802:10811:52820:57831:54841:35851:23861:54870:52882:05895:09902:01911:45921:37930:42942:16951:18961:29971:15981:01991:071000:361011:111022:481032:071044:041054:131065:081074:211081:371093:331101:011111:101121:221130:591140:511151:531161:551170:181182:4311916:011200:421210:481220:571230:381240:491250:491260:431270:481280:471290:561300:501310:371321:551330:341340:261352:041362:151371:061381:061392:461401:391411:251421:071431:381442:041452:021461:101471:591481:361491:021500:41