Listen to this chapter • 0:58
[1] Olúwa, báwo ni àwọn ọ̀tá mi ṣe pọ̀ tó báyìí! Báwo ni àwọn ti ó dìde sí mi ṣe pọ̀ tó!
[2] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó ń sọ ní ti tèmi, pé “Ọlọ́run kò nígbà á là.” Sela.
[3] Ṣùgbọ́n ìwọ ni asà yí mi ká, Olúwa; ìwọ fi ògo fún mi, ìwọ sì gbé orí mi sókè.
[4] Olúwa ni mo kígbe sókè sí, ó sì dá mi lóhùn láti orí òkè mímọ́ rẹ̀ wá. Sela.
[5] Èmi dùbúlẹ̀, mo sì sùn; mo sì tún padà jí, nítorí Olúwa ni ó ń gbé mi ró.
[6] Èmi kì yóò bẹ̀rù ẹgbẹẹgbẹ̀rún ènìyàn tí wọ́n rọ̀gbà yí mi ká.
[7] Dìde, Olúwa! Gbà mí, Ọlọ́run mi! Lu gbogbo àwọn ọ̀tá mi ní àgbọ̀n; kí o sì ká eyín àwọn ènìyàn búburú.
[8] Láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìgbàlà ti wá. Kí ìbùkún rẹ wà lórí àwọn ènìyàn rẹ. Sela.
Ìwé Saamu — Chapters
10:5621:2230:5841:1951:4961:2072:0481:0792:25102:34111:04121:09130:54141:05150:51161:29172:05185:58191:59201:12211:43224:09230:53241:16252:27261:25272:13281:23291:10301:38313:22321:41332:15342:26353:48361:38374:42382:24392:05402:57411:39422:01431:00443:10452:27461:24471:03481:40492:29502:49512:28521:31531:10541:05553:08561:46571:48581:35592:36601:46611:02621:42631:23641:27651:54662:09670:52684:40694:17700:51712:59722:36732:54742:48751:24761:32772:22787:13791:45802:10811:52820:57831:54841:35851:23861:54870:52882:05895:09902:01911:45921:37930:42942:16951:18961:29971:15981:01991:071000:361011:111022:481032:071044:041054:131065:081074:211081:371093:331101:011111:101121:221130:591140:511151:531161:551170:181182:4311916:011200:421210:481220:571230:381240:491250:491260:431270:481280:471290:561300:501310:371321:551330:341340:261352:041362:151371:061381:061392:461401:391411:251421:071431:381442:041452:021461:101471:591481:361491:021500:41