Skip to content
Opens in a new window
Listen to this chapter • 6:50

[1] Adamu, Seti, Enoṣi,

[2] Kenani, Mahalaleli, Jaredi,

[3] Enoku, Metusela, Lameki, Noa.

[4] Àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti.

[5] Àwọn ọmọ Jafeti ni: Gomeri, Magogu, Madai; Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi.

[6] Àwọn ọmọ Gomeri ni: Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.

[7] Àwọn ọmọ Jafani ni: Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu.

[8] Àwọn ọmọ Hamu ni: Kuṣi, Ejibiti, Puti, àti Kenaani.

[9] Àwọn ọmọ Kuṣi ni: Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka. Àwọn ọmọ Raama: Ṣeba àti Dedani.

[10] Kuṣi sì bí Nimrodu ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.

[11] Ejibiti sì bí Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu,

[12] Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.

[13] Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀, àti Heti,

[14] àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi,

[15] àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini,

[16] àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati.

[17] Àwọn ọmọ Ṣemu ni: Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu. Àwọn ọmọ Aramu: Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki.

[18] Arfakṣadi sì bí Ṣela, Ṣela sì bí Eberi.

[19] Eberi sì bí ọmọ méjì: ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.

[20] Joktani sì bí Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera.

[21] Hadoramu, Usali, Dikla,

[22] Ebali, Abimaeli, Ṣeba.

[23] Ofiri, Hafila, àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani.

[24] Ṣemu, Arfakṣadi, Ṣela,

[25] Eberi, Pelegi. Reu,

[26] Serugu, Nahori, Tẹra,

[27] àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu).

[28] Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli.

[29] Èyí ni àwọn ọmọ náà: Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu,

[30] Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema,

[31] Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Iṣmaeli.

[32] Àwọn ọmọ Ketura, obìnrin Abrahamu: Simrani, Jokṣani Medani, Midiani Iṣbaki àti Ṣua. Àwọn ọmọ Jokṣani: Ṣeba àti Dedani.

[33] Àwọn ọmọ Midiani: Efani, Eferi, Hanoku, Abida àti Eldaa. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Ketura.

[34] Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki. Àwọn ọmọ Isaaki: Esau àti Israẹli.

[35] Àwọn ọmọ Esau: Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora.

[36] Àwọn ọmọ Elifasi: Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi; láti Timna: Amaleki.

[37] Àwọn ọmọ Reueli: Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa.

[38] Àwọn ọmọ Seiri: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani.

[39] Àwọn ọmọ Lotani: Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani.

[40] Àwọn ọmọ Ṣobali: Afiani, Manahati, Ebali, Ṣefo àti Onamu. Àwọn ọmọ Sibeoni: Aiah àti Ana.

[41] Àwọn ọmọ Ana: Diṣoni. Àwọn ọmọ Diṣoni: Hemdani, Eṣbani, Itrani, àti Kerani.

[42] Àwọn ọmọ Eseri: Bilhani, Saafani àti Akani. Àwọn ọmọ Diṣani: Usi àti Arani.

[43] Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Edomu, kí ó tó di pé ọba kankan jẹ lórí Israẹli: Bela ọmọ Beori, orúkọ ìlú rẹ̀ ni Dinhaba.

[44] Nígbà tí Bela kú, Jobabu ọmọ Sera ti Bosra sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

[45] Nígbà tí Jobabu kú, Huṣamu láti ilẹ̀ Temani sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

[46] Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi ọmọ Bedadi tí ó kọlu Midiani ní ìgbẹ́ Moabu, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Afiti.

[47] Nígbà tí Hadadi sì kú, Samla láti Masreka, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

[48] Samla sì kú, Saulu ti Rehoboti létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

[49] Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

[50] Nígbà tí Baali-Hanani kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau; orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu.

[51] Hadadi sì kú pẹ̀lú. Àwọn baálẹ̀ Edomu ni: baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti

[52] baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni.

[53] Baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari,

[54] Magdieli àti Iramu. Àwọn wọ̀nyí ni baálẹ̀ Edomu.

Ìwé Kronika Kìn-ín-ní — Chapters